[Audio + Lyrics] Jesu Ore Otito – Tope Alabi Hymnal

Tope Alabi Hymnal Vol. 1 Album
Gospel Songs Mp3

Stream the official Audio “Jesu Ore Otito” from Tope Alabi Hymnal album 2020

Lyrics: Jesu Ore Otito

Verse 1
Wa sodo re yio gba o
Oun nikan ni mole to tan so kunkun
Oro re iye, o n gba ni la
Ko tun sona miran tole gbani

Chorus
Jesu jesu ore otito
Jesu kristi iye loro re
Otan mole so kunkun u aye wa
Enito gba jesu loni iye.

Verse 2
Wa ma sonu, aye jin na
Oun nikan lole rin o sebute
Aye so kunkun, jesu ni mole
Gbagbo yio mu o debi isimi

Verse 3
Faye re fun, fokan re fun
Mase je kona re mo loju re
Oluwa n kan lekun, ore ma se aya
Ayo la o fi ba jesu joba

Verse 4
Oun adun ni keru wiwo di itan
Alafia ti aye kori ni
Ifokanbale irorun, eyi to logo
La jogun fawon toluwa gbala

DOWNLOAD MP3

Orode Moses
the authorOrode Moses
Gospel Blogger | Music Promoter | Lover Of The Gospel || Web Developer/Designer | I.T Consultant. For Enquirer Call/WhatsApp: +2347036304545.

Leave a Reply