Taiwo Esther releases a brand new single titled “Baba Olugbeja” produced by PMP. A song of prayer that encourages everyone to ask for God’s intervention in the affairs of our country and also a song of powerful prayer for yourself.
Listen, Download and Enjoy
Baba olugbeja,omo olugbeja, Emi mimo olugbeja ni oo, Gbejamija kojo to pe(2*)
Oba to gbe jefta nija, agbara re wa sibe sibe, iwo to gba omo isreali la lowo fara o, oba olugbeja nibo loju re wa
Oba olugbeja nibo loju re wa, Alaini npari wo,olosi nfi gbeta gbeja wa ja, won pe eniyan Lori lede yi bi eni peran, oba olugbeja nibo loju re wa(2*)
Arin nile, inu nbi elesin, Atun wo akisa inu nbi alaso o igba wo la o seyi da olorun, oba olugbeja dakun gbe ija wa je
Call: Ariwo lotun Ariwo losi yi o ti to ge
Rep: gbeja wa ja
Call: itaje sile orilede Yi baba oti to ge o
Rep: gbeja wa ja
Call: Kawa ninu ile kerun tunma bani
Call: Ariwo lotun Ariwo losi yi o ti to ge o
Call: herodu to foju di o lojosi o fara gbegba
Call: Nebukadinesari foju di o o fara gbegba
Call: Ejo kekeke ogbe nila mi o
Call: O foju di o o fe mo iru oba to je oooo
Call: baba olugbeja wa gbeja wa je oooo
Call: Eru jeje oba,daku gbeja wa je
Call: ogbeni nija keru obani to nija ………….