DOWNLOAD FREE MP3
GOSPELMINDS TELEGRAM

Lyrics: Dunni Dada – Iyanu

Dunni Dada – Iyanu
Gospel Songs Mp3

IYANU by Dunni Dada

[Chorus:] Loruko Jesu
Loruko Jesu
Iyanu yio sele
Loruko Jesu
Loruko Jesu
Iyanu yio sele
oo iyanu yio sele ooo
iyanu yio sele[Verse 1]:
se o ti gbo nipa obinrin orisun eje
to fowokan iseti aso Oluwa
Oluwa si mu larada
o gba’wosan re
eyi lo fi han wipe
iyanu yio sele[Chorus:] [verse 2:] se o ranti om’okunrin Lazaru
to ku fun ojo merin
Oluwa lo s’ibi iboji re
O pe oruko re, o siji dide
oku ojo merin o dale laye
eyi lo fi han wipe
iyanu yio sele[Chorus:] [Verse 3:] se o ranti opo sarafuti
ti awon onigbese fe m’awon omo re lo
ti Oluwa ti se yanu ororo
akun wo sile
oro Oluwa ti so fun wa wipe
bi awa ba le gbagbo
awa yio ri ogo Oluwa
se o gbagbo
(modulation)
se o gbagbo
iyanu yio sele

loruko Jesu (loruko Jesu)
loruko Jesu
iyanu yio sele (iyanu iyanu ooo)
loruko Jesu (iku gb’oruko re o sa)
loruko Jesu
iyanu yio sele (arun gb’oruko re o wo ile)

call:Iyanu Res: iyanu
call:to the woman in need of a miracle Res: iyanu
call:to the man in need of a breakthrough Res: iyanu yio sele
call:e e e e e e Res: iyanu
call:dont give up now Res: iyanu
call:only believe Him Res: iyanu yio sele

loruko Jesu (Oba to silekun ti ko s’enito leti)
loruko Jesu (Oba to tilekun ti ko s’enito lesi)
iyanu yio sele (Baba mi, lo le pa ti ko s’enito leji)
loruko Jesu
loruko Jesu
iyanu yio sele (ko ma sohun t’Oluwa ko le se)
loruko Jesu (Loruko Jesu)
loruko Jesu (Loruko Jesu)
iyanu yio sele (iyanu, iyanu, iyanu eee)
loruko Jesu (iyanu loruko baba mi)
loruko Jesu (apa nla to so’ri aiye ro)
iyanu yio sele (erujeje….)

Download, Listen and Share!!!

Click To Download Mp3 File Size: 5:0

Follow Us Twitter | Like Our facebook Page | Follow Us On Instagram

Play Dunni Dada – Iyanu

Leave a Reply