DOWNLOAD FREE MP3
GOSPELMINDS TELEGRAM

Music + Lyrics: Tope Alabi – Eyin Oluwa, Halleluyah

Tope Alabi Hymnal Vol. 1 Album
Gospel Songs Mp3

Listen and download the official Audio “Eyin Oluwa, Halleluyah” from Tope Alabi Hymnal album 2020

Lyrics: EYIN OLUWA HALLELUYAH

Verse 1
Eje ka f;ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai

Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah

Verse 2
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun

Verse 3
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo

Verse 4
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo

DOWNLOAD MP3

Leave a Reply